Chorus:
Atupa mi o ni ku
imole mi ko ni d'okunkun
Baba imole mbe ni 'rin ajo mi
to nba mi rin 'rin ajo.
Vocal
Mo ni baba kan
nipase Re la da ohun gbogbo
leyin re, ko s'ohun ti a da
ninu re ni iye wa (ewo)
iye naa ni imole
t'okunkun ko le bori (Tori)
Baba imole...
- Producer:VICTORIA JAYEOBA
- Release Date:June 18, 2024




