Uploaded By
VIEW PROFILE
650 Followers
(1st Verse)
I no think twice, mi ò le rònu pa ara mi
Cause how e go be, I dey think sometimes
Ìrònú yìí pọ̀, mi ò le dá gbé sórí
But I go do it all myself, cause na nobody concern
I no wan trespass, no wan see gobe
Slow and steady, I know say e go tey
Ìrétí pípé o ló ń múni ṣe àìṣe
So make e no go tey, kó tó bá mi gbé dé
(Pre Chorus)
Then I focus on the mula, mo dẹ jára mi tán
I wanna get the mula k'áyé má rí mi tán
Ọ̀rọ̀ inú wọn má tún pọ̀ jù ti ejò lọ
But dem no go let you know, wọn a tún bá ẹ fẹyín gán
I go face my handwork, Yahoo combine
What people say no be my concern
And if I get this money, mo máa gbé short time
Since I've been hustling for the payday as been a long time
{CHORUS}
Say, ó má dá, Àjẹ́ ó máa dá
This suffering no matter
Àsìkò l'ayé, ìka wa ò dọ́gba
So I steady on my hustle kí n lè dúró dáadá o
Ó má dá, Àjẹ́ ó máa dá
This suffering no matter ò
Àsìkò l'ayé, ìka wa ò dọ́gba
So I steady on my hustle kí n lè dúró dáadá o
(2nd Verse)
Dem say man wey no get money ò kìí ṣe ọkùnrin
The girlfriend wey I trust sef tún dẹjú mọ́ mi
Èmi náà ni o, wọn ò ní fi mí ṣe ẹlòmíì
Where my mate don dey spend, kí n má ṣe f'ọwó́ b'ójú mi
I n
- Release Date:June 27, 2026
- Producer:TGV Studio
- Genre:Afrosounds
