|
|
Upload
E E Soro || TrendyBeatz.com by Dagrin
E E Soro || TrendyBeatz.com by Dagrin

DagrinE E Soro || TrendyBeatz.com

DagrinE E Soro || TrendyBeatz.com

0:00
0.00% played
0:00

Uploaded By

VIEW PROFILE
Avatar

372 Followers

Ẹyin témí Mó mọ pé ẹ ti ń retí mí ti pé Ẹlòmíì rò pé mó tí kù, mọ tí kù sí pańpẹ́ But mọ dupẹ wípé mi ti deni yẹpẹ É bami ji Tolulope kò wá bá mi sọ pé Àwọn èèyàn o mọ mi, wọn pe ni ináà Won ni mo f'ori, f'imu mi jo Obinna Ọmọ Yorùbá ni mí Wọn bimi pelu ayọ' Mọ ti sọ fún yín pe ki e ye pè mí ni Anayo Àwọn èèyàn ṣòro, wọn ni mi o gbó òyìnbó Mọ'fé bẹ'rẹ' lọwọ yin, se òyìnbó gbó Yorùbá? Mi ó sé ọmọ NewYork Ọmọ Èkó ni mí ti e ba ti rimi ewo ko need ki e bí mi Ó fe mó Ẹbí mí, ó fẹ' mó màmá to bí mi Mo fun e láyé, kò lo bẹ'rẹ' lọ'wọ' Baby mi, a ṣàlàyé bi mo se je aráyé Ìjọ kàn náà kò ni wọn bi emi pẹlu Falaye Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ' Yín ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòro Mọ' dé ti wọlé dé ní yẹn, É sọ'rọ' É sọ'rọ', É sọ'rọ' Eyín tèmi, mọ' wọlé de, É sọ'rọ' Ẹyin ti e tin rẹ tí mi tipe, É ṣòr
  • Release Date:December 26, 2023
  • Album:The Genesis Of C.E.O
  • Producer:Dagrin
  • Genre:Afrosounds
523Total plays
4Likes
4Playlist Adds

Playlists Featuring Artist

0 comments