Uploaded By
VIEW PROFILE
60 Followers
Akoko adua wa fun rira igba pade nitori buburu ni gbogbo ojo. Akoko ti a ma ngbori le aya baba wa lorun lati gbo ohun to nlo ni okan re. Wakati adua didun ni igba ayo ati isegun to daju, apeere igbagbo wa to gbile ninu Oluwa wa Jesu Kristi.
- Release Date:May 1, 2026
- Producer:Alafiafunmi Oni, Benjamin Bakare
- Genre:Gospel




