|
|
Upload
Ara by Queencilla
Ara by Queencilla

QueencillaAra

QueencillaAra

0:00
0.00% played
0:00

Uploaded By

VIEW PROFILE
Avatar

305 Followers

Ìràwọ̀ mi Tó mi tán Kò lè ever kú Never never Lie lie Kole ku Pass me di omela “Kí àwọn tèmi má ṣà faji lọ” Jo Jo Mo ti mo Ti mo fe Mi o fi Wahala Pa ara mi Never Cause Aye Kere bintin Ni mo kpe Ejika Mi o ri ro I WO lo ni Ewa re Ko je ki Ewa re Ma ro e Ara mo da Kon Sa pe mo fi gara Iba da Tí o bá ṣe iṣẹ́ tó dára Ooh You know Aja WO Ewu Oro sho O di fila si o Ẹni ṣọ́wọ́ ni jèrè Ijapa ologbon ofi Iwa Omo de meta Wọ́n ń ṣeré Ori Ota Meta.”
  • Release Date:March 20, 2026
  • Producer:Mvpbeatz
  • Genre:Afrosounds
182Total plays
4Likes

Playlists Featuring Artist

0 comments