Track 1: NINU JESU
Chorus : Igbekele mi ninu Jesu, Oluwa
Igbekele mi
Ninu Oluwa lo wa a a a
Otogbokanle
Otosimile
Jesu oo se o
Ninu re ni igbekele mi
Jesu o se o
Ninu re ni
Igbekele wa
1. Igbekele mi ninu Oluwa
Igbekele mi ninu Oluwa ni
Bi aye sa bi won fo
Aduro ti...
- Release Date:October 31, 2025




