Uploaded By
VIEW PROFILE
245 Followers
ORIN TUNTUN
Fìrìgbòn ò s’ílèkùn eni oníbodè bá fún n kókóró è ló má si.
Omi tuntun ti rú, eja tuntun ti wonú è lo èyin eja àtijó ó ti yá e bìlà
A bì Oba rán o nísé o lódò obà kún o jé lo yá kenó (canoe) kó o má baà fowó pojú idà Oba.
Àmó ojó ojókan n bò tíkún ó peran, tópòló ó peran, tíyàwó ó lota, tí ò ní je níbè, sùn níó ma wò, àdùn fowó òsì nujúnù
Hmmmmm rere ni n ó se, torí ohun gbogbo tí a bá jé láyé yìí esè méfà náà ni rere ni kí o se.
Ó bérù re níbodè rere ni kí o se.
Bami gbe bamigbe ayamin ja
.
Omi tuntun ti ru eja tutun wole o
Onibode shi ilekun o
Bami shi ilekun o
Orin tuntun ti de ire wolemiwa o
Onibode shi ilekun o
Baba shi ilekun o
.
Modade oba mo wo ewu oye o
Mo wewu Oge mo fi Ojo si mo pakurumo mo mo jo dada Mo yanfanda mofi ijo ti 2x
Eja Loni ibu Eye Loni Igbo
Deeeu
- Release Date:November 10, 2021
- Producer:WHALEZ
- Genre:Afrosounds






0 comments