Uploaded By
VIEW PROFILE
1.17K Followers
LYRICS:
An Taloni kewu titan
Baba lagege baba lorile nko
An etelemi kalo si oko afo
Tobalu ni badia tobalu ni igbanla
An Alasalatu ijoya
Eyonbo anobi ebamiki onishenla
An omo ilekewu ijoya
Egbe olohun tobi lailah ah ilahla
Awontonibo lafegba
Amatoriwon satira
Tonbatunfe shewanika
Amatun wole aluwa
Kul huwa allahu fun awon alfa wa totilo
Alujona latorofun gbogbo won
Tori Koseni tani bawoni tiwonsheje
Awontobe laye jeka riwonpe o
An Taloni kewu titan
Baba lagege baba lorile nko
An etelemi kalo si oko afo
Tobalu ni badia tobalu ni igbanla
An Alasalatu ijoya
Eyonbo anobi ebamiki onishenla
An omo ilekewu ijoya
Egbe olohun tobi lailah ah ilahla
1.Alh Waheed eleyele amir aqwam international
2.Alfa jamiu amir iqwan
3.Alfa Al aswad ameed dawah
4.engineer bashiru
5.alfa Yus
- Release Date:November 18, 2024
- Album:Abanikanda
- Genre:Afrosounds






0 comments