Uploaded By
VIEW PROFILE
25 Followers
gospel hymns
Baye ba nfa mi pelu ogo re
Ko sewu Omo Olorun ni mi
Owo agbara Re yo di mi mu
Lojo aye mi gbogbo
Mo lore t'O npese faini gbogbo
Mo nile kan loke orun giga
Wo! Nitori idi eyi na ni
Emi se nko Aleluya
Emi ko je gbagbe pe lor'igi
Ni Omo Olorun gbe ku fun mi
Ko le saiku lati gbokan mi la
Ko tun si ona miran
Un o j'oloto s'Oluwa Oba mi
Un o ma korin 'yin si nigbagbogbo
Mo mo pe nikehin On yo gba mi
Lati ma ba gbe titi.
- Release Date:July 14, 2025
- Genre:Gospel





