Uploaded By
VIEW PROFILE
1.25K Followers
THE SONG LYRICS
CHORUS
Baba mi, d’igi ti o gbodo j’abo
Baba mi, d’igi ti o gbodo fo
Baba mi, Ejika ti o gbo ye o
O ku itoju mi
E mape l’aaye fun wa
Tori Na
Mo K’ira fun baba
Mo K’ira fun baba o
Mo K’ira fun baba mi
Mo K’ira fun baba fun baba o
Atona ire!
VERSE
I Remember when I was young he look out for me
He thought me to be brave, he thought me to be strong
Baba lo wo mi d’agba
Ohun lo so mi d’omo
Baba lo wo mi d’agba
L’oso mi d’omo
Atona ire!
E Kira fun.
CHORUS
Mo K’ira fun baba
Mo K’ira fun baba o
Mo K’ira fun baba mi
Mo K’ira fun baba fun baba o
Atona ire!
BRIDGE
Baba ni d’igi baba l’awo ran
Ohun lo toju mi lati kekere o
Baba ni d’igi baba l’awo ran
Abiamo o ku itoju mi
Baba ni d’igi baba l’awo ran
Ema d’agba, darugbo fun wa, torina…
Mo K’ira fun baba
Mo K’ira fun baba o
Mo K’ira fun baba mi
Mo K’ira fun baba fun baba o
Atona ire!
Ero b’ami ki Baami
Ero b’ami ki Baami o
Ero b’ami ki Baami
Po ku oro omo 2X
Mo K’ira fun baba
Mo K’ira fun baba o
Mo K’ira fun baba mi
Mo K’ira fun baba fun baba o
Atona ire!
Music Composed / Arranged by BAYO ADEEYO AKA BAYO ODODO
- Release Date:June 15, 2026
- Genre:Afrosounds





